Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2023

Question 7

 

Nínú Oríkì Ìran Onígbòórí”, rọ́ ìtàn bí ìyá Mọ̀sè ṣe di ọlọ́mọ.

Observation

 

Candidates were required to narrate the story of how ìyá Mọ̀sè became a mother as evident in the oral poetry.

Bí Ìyá Mọ̀sè ṣe di ọlọ́mọ:

  1. Ìyá Mọ̀sè ló tẹ Ìgbórí dó
  2. Àgàn ni ìyá Mọ̀sè
  3. Ìyá yìí ti dàgbà/dògbó/léwú lórí
  4. Ó máa ń sunkún àìrọ́mọbí
  5. Ó ń fi ọwọ́ osùn tútù nu ògiri gbígbẹ/kò rí oyún ní/ó ń ṣe nǹkan oṣù láà lóyún
  6. Ó ń ṣọ̀fọ̀ ara rẹ̀ láìkú
  7. Amúṣàn-án yọjú nínú odò Asà
  8. Amúṣàn-án wá bú ọpa ó ní ìyá Mọ̀sè yóò finú ṣoyún, yóò sì fẹ̀yìn gbọ́mọ pọ̀n/ó ní ìyá Mọ́sè yóò bímọ ti ara rẹ̀
  9. Ìyá Mọ̀sè sì bí Ẹ̀gùn Ànùmí
  10. Báyìí ni ìyá Mọ́sè ṣe di ọlọ́mọ

 

Most candidates who attempted this question showed a lack of knowledge of the prescribed text: Babalọlá’s Àwọn Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n.