Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2020

Question 2

 

Kọ  Àpẹẹrẹ  àwọn ọ̀rọ̀ Yorùbá mẹ́ta mẹ́ta tí ó bá irúfẹ́ bátánì wọ̀nyí mu

(a)KF – F

(b)KF – F – KF

(d)  F – F – KF
(e)  KF – N – KF
(ẹ)  KF – KF – KF


Observation

 

Candidates were required to provide 3 Yoruba words for the given syllable structures.

Àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀ Yorùbá mẹ́ta mẹ́ta tí ó bá irúfẹ́ bátànì wọ̀nyí mu:
(a)      K F – F: náà, bẹ́ẹ̀, káà, ṣíọ̀, fùú, sùù, fòò, bíà, yìí.
(b)     K F – F – KF: bẹẹrẹ, ṣáájú, béèrè, sùúrù, bẹ́ẹ́rẹ̀, dáódù, ráágó, bọ́ọ̀lù, góòlù.
(d)     F – F – KF: èèwọ̀, eérú, òògùn, èébú, ọ̀ọ̀lẹ̀, àánú, èérí, aájò, èémí, èèrí, àìrí.
(e)     KF – N – KF: gban̄gba, kọ̀ǹkọ̀, fúnn̄kẹ́, bíńtín, géńdé, bím̄pé, wán̄dé, pan̄la.
(ẹ)     KF – KF – KF: kókóró, kékeré, kedere, kodoro, pẹrẹsẹ, pelemọ, kúlúsọ, kọ́kọ́rọ́.

 

Most candidates missed the answers because of their nonchalant attitude to the spelling of the tones, especially the need to indicate the midtone with a macron on the syllabic nasals (n̄, m̄). The performance was fair.


.