Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2021

Question 9

 

 

Ìhà wo ni Mọrèmi kọ sí orò tí wọ́n ṣe fún òkú bàbá Àyànná?

Observation

 

 

 

Candidates were required to discuss Mọrèmi’s reaction to the burial rite of Àyànná’s father.

 

Ìhà tí Mọrèmi kọ sí orò tí wọ́n ṣe fún òkú bàbá Àyànná:

 

  1. Wọ́n ránṣẹ́ pe Àyànná pé bàbá rẹ̀ kú
  2. Mọrèmi àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ tẹ̀le e lọ sí ibi ìsìnkú náà
  3. Wọ́n ṣe orò ìsìnkú fún bàbá Àyànná
  4. Mọrèmi wa ara ro níbi tí ó dúró sí
  5. Ó káwọ́ pọn àyà
  6. Ó ń wò duu bí adìẹ tí ẹyin fọ́ mọ́ nínú
  7. Gbogbo ara rẹ̀ gbóná girigiri bí ajere, ó sì ń sẹ́gìíìrì léraléra
  8. Ara bẹ̀rẹ̀ síí kan án, ó sì ń fi ìkanra hàn
  9. Ó ka ètùtù náà sí èyí tí ó burú jáì tí kò sì yẹ kí á máa bá láàárín àwọn ènìyàn láwùjọ
  10. Èyí mú kí Mọrèmi ṣe ìpàdé pàjáwìrì pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀
  11. Mọrèmi gbara ta pé kò yẹ kí wọ́n máa mú obìnrin sìn bí ẹrú láwùjọ
  12. Ó ṣe ìpinnu pé obìnrin ilẹ̀ Ifẹ̀ gbọ́dọ̀ ja ìjà òmìnira.

 

Candidates’ performance in this question was commendable.