Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2021

Question 7

 

 

Nínú oríkì “Ìran Olúfọ́n”, báwo ni Aláàfin ṣe gba adé Òrèlú?

Observation

 

 

 

Candidates were required to narrate how the Aláàfin got the crown of Orèlú as described in the poem of this lineage.

 

Bí Aláàfin ṣe gba Ade Òrèlú nínú oríkì “Ìran Olúfọ́n”

 

  1. Aláàfin làgbà, òun ni Àrẹ̀mọ
  2. Aláàfin kì í gbélé
  3. Wọ́n pín adé nígbà tí Aláàfin kò sí ní ilé
  4. Wọn kò pín adé fún Aláàfin
  5. Ìgbà tí Aláàfin darí dé sí ilé láti ibi tí ó lọ, ó béèrè pé adé tí òun dà?
  6. Òrèlú nìkan ni ó kù nílé nínú gbogbo àwọn tí wọ́n pín adé fún.
  7. Wọ́n bá gbé adé Òrèlú lọ (rèé) fún Aláàfin
  8. Báyìí ni Aláàfin ṣe gba adé Òrèlú

 

The candidates who attempted this question performed poorly.