Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2021

Question 2

 

Lo bátànì ìhun sílébù láti fi pín ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀rọ̀ wọ̀nyí:

 

(a)      pándọ̀rọ̀;
(b)     kedere;
(d)     Ọláìítán;
(e)      Láníyọnu;
(ẹ)      Akéréle;
(f)      Babalọ́lá;
(g)     Ọlálékan;
(gb)    Adéróunmú;
(h)     kọ̀ǹkọ̀;
(i)      Ajéèégbé.

Observation

 

 

Candidates were required to use syllabic pattern for syllabic analysis of the given data:

 

         

 

Ọ̀rọ̀

Bátànì Ìhun Sílébù

a.

Páńdọ̀rọ̀

KF/N/KF/KF

b.

Kedere

KF/KF/KF

d.

Ọláìítán

F/KF/F/F/KF

e.

Láníyọnu

KF/KF/KF/KF

ẹ.

Akéréle

F/KF/KF/KF

f.

Babalọlá

KF/KF/KF/KF

g.

Ọlálékan

F/KF/KF/KF

gb.

Adéróunmú

F/KF/F/F/KF

h.

Kọ̀ǹkọ̀

KF/N/KF

i.

Ajéèégbé

F/KF/F/F/KF

 

 

Many of the candidates who attempted this question could not use the syllabic pattern for syllabic analysis of the given data, this led to poor performance.