Yoruba Paper 2 WASSCE (PC 1ST), 2021

Question 10

    Nínú ewí Èèpà Ń Para Rẹ̀, àwọn wo ni akéwì fi wé èèpà?


Observation

Candidates were required to mention various people compared with the fleaas stated in the poem “Èèpà Ń Para Rẹ̀.

Àwọn tí akéwì fi wé Èèpà nínú ewì “Èèpà ń para rẹ̀”:

  1. ọ̀dọ́kọ, aṣẹ́wó, olówò nàbì
  2. ológe òṣì, ológe òfò
  3. akẹ́kọ̀ọ́ tó ń mugbó mu sìgá
  4. akẹ́kọ̀ọ́ tó ń ṣèjàngbọ̀n
  5. elérépá òṣì
  6. ẹni tí ó ń kọrin jupájupá kiri
  7. afàìṣadélébọ̀ ná ilé àwọn fètò (sí ọmọ bíbí)
  8. akẹ́kọ̀ọ́ tó wọ ẹgbẹ́ òkùnkùn
  9. akẹ́kọ̀ọ́ tó ń tẹ fóònù dípò kó kàwé
  10. akẹ́kọ̀ọ́ tó ń gbé owó ilé-ẹ̀kọ́ ná
  11. akẹ́kọ̀ọ́ tí a ti lé ní ilé-ẹ̀kọ́ tí kò lọ sílé
  12. akẹ́kọ̀ọ́ tó ń tilé-ẹ̀kọ́ lọ polon̄go ìbò
  13. akẹ́kọ̀ọ́ ọ̀kàwé ṣe tọ́ọ̀gì òṣèlú

Candidates’ performance was poor, general guesses were made and not as evident in the text.