Yoruba Paper 2 WASSCE (PC), 2023

Question 5      Fi àpẹẹrẹ mẹ́ta mẹ́ta ṣàlàyé ọ̀kọ̀ọ̀kan àtúnpín ìsọ̀rí ọ̀rọ̀-orúkọ wọ̀nyí:

  1. Pa àtẹ ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò olùwà àti ẹ̀yán
Lo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ẹ̀yán ní gbólóhùn kí o sì fa ìlà sí ìdí ọ̀rọ̀ tí o lò ní gbólóhùn

Candidates were required to draw a chart of pronouns in subject and qualifier position in (a) and use the pronoun qualifiers in illustrative sentences in (b).

 

 

Àtẹ ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò olùwà, ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò ẹ̀yán àti ìlò wọn nínú gbólóhùn:

            (ai) Àtẹ Ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò olùwà


S/N

ẸNI

ẸYỌ

Ọ̀PỌ̀

a

kínní

mo

a

b

kejì

o

d

kẹta

ó

wọ́n

 

(aii) Àtẹ Ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò ẹ̀yán


S/N

ẸNI

ẸYỌ

Ọ̀PỌ̀

a

kínní

mi

wa

b

kejì

rẹ/ẹ

yín

d

kẹta

rẹ̀/ẹ̀

wọn

 

  1.      Ìlò ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò ẹ̀yán nínú gbólóhùn
  2. Ọmọ mi ni Adéolú.
  3. Ilé rẹ/ẹ ni mò ń bọ̀.
  4. Aṣọ rẹ̀/ẹ̀ mọ́ tónítóní.
  5. Ọkọ̀ wa kò sáré./Olú sùn sí ilé wa.
  6. Ẹ gba ẹ̀bùn yín.
  7. Ọ̀rọ̀ wọn kò tète yé mi.

 

Candidates failed to use the pronouns in illustrative sentences and this led to loss of marks.