Yoruba Paper 2 WASSCE (PC 2ND), 2022

Question 7

    Nínú oríkì “Ìran Alápà”, dárúkọ àwọn oríṣi Ògun àti àwọn ohun tí wọ́n fi ń bọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.


Observation

Candidates were tasked to identify the different forms of the Ogun deity in this lineage and mention the symbol of worship for each of the different forms of the deity.

Oríṣi Ògún tí wọ́n bọ àti ohun tí wọ́n fi ń bọ wọn nínú oríkì “Ìran Alápà”


S/N

Oríṣìí Ògún

Ohun tí wọ́n fi ń bọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọ́n

i

Ògún Ènírá

Ẹran ajá

ii

Ògún Ajerò

Àgbò

iii

Ògún enígbàjámọ̀

Irun

iv

Ògún alápatà

Ẹ̀jẹ̀ ẹran

v

Ògún eníkọlà

Ìgbín

vi

Ògún gbẹ́nàgbẹ́nà

Oje igi

vii

Ògún alágbẹ̀dẹ

Èédú arọ́

The candidates who attempted this question performed poorly. This shows poor knowledge of the set text.