Question 4
Sọ ìsọ̀rí  ọ̀rọ̀ tí àwọn ọ̀rọ̀ kọ̀ọ̀kan tí a fàlà sí nídìí nínú gbolóhùn wọ̀nyí  wà.
      (a)      Wàhálà Olú pọ̀.
      (b)     Mo pa ̀kì ara mi.
      (d)      Má wàhálà mi.
      (e)     Àwọn tí à ń retí ti dé.
      (ẹ)     Ọmọ  wù mí.
      (f)     Bọ́lá Ìbàdàn ga ju Bọ́lá Èkó lọ.
      (g)    Aṣọ pupa ni Olú wọ̀.
      (gb)  Ẹ̀bùn wà ní inú mọ́tò.
      (h)   Ó se iṣu ṣùgbọ́n kò jẹ ẹ́
      (i)   Ilé wa ni Bísí ń gbé.
Observation
Candidates were required to state the  grammatical class of the underlined words in 
each sentence.  
Ìsọ̀rí  àwọn ọ̀rọ̀ tí a fàlà sí nídìí 
    (a) ọ̀rọ̀-orúkọ
    (b) ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ/ọ̀rọ̀-orúkọ
    (d) ọ̀rọ̀-ìṣe
    (e) ọ̀rọ̀-arọ́pò-afarajórúkọ/ọ̀rọ̀-orúkọ
    (ẹ) ọ̀rọ̀-arópò-orúkọ/ọ̀rọ̀-orúkọ
    (f) ọ̀rọ̀-orúkọ
    (g) ọ̀rọ̀-àpèjúwe
    (gb) ọ̀rọ̀-atọ́kùn
    (h) ọ̀rọ̀-asopọ̀
    (i) ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ/ọ̀rọ̀-orúkọ
    Most  candidates who attempted this question performed fairly well while a few of  them mistook grammatical classes for word classes.
  
