Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2019

Question 4

 

(a) Kí ni ọ̀rọ̀-asopọ̀?
(b) Kọ àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀-asopọ̀ márùn-ún kí o sì lo ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn níṅú gbólóhùn.

 

Observation

 

Candidates were required to define conjunctions/disjunctions in (a), mention 5 examples of conjunctions/disjunctions and use each of them in sentences in (b).
Ọ̀rọ̀-asopọ̀ ni àwọn wúnrẹ̀n tí à ń lò láti so ọ̀rọ̀ tàbí gbólóhùn pọ̀.

(bi) Àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀-asopọ̀
(i) pẹ̀lú
(ii) òun
(iii) àti
(iv) sì
(v) àyàfi/àfi
(vi) ańbèlèǹté/ańbèlèǹtàsé/ ańbọ̀sìbọ́sí/ańbọ̀sì
(vii) ṣùgbọ́n/àmọ́
(viii) yálà...tàbí
(ix) bẹ́ẹ̀ ni
(x) tàbí/àbí

Majority of the candidates recalled the definition of conjunction/disjunction in (a), gave accurate examples in (b) and also used the conjunctions/disjunctions in sentences. Candidates’ performance in question 4 was commendable.