(a) Fa awon olori awe-gbolohun ati  awe-gbolohun afarahe yo ninu awon gbolohun wonyi.
                        
                         (i) bi mo ba lowo, n o gbadun aye yii;
                           (ii) oko ti Olu sese ra rewa gan an;
                           (iii) so bi ija naa se sele fun mi;
                           (iv) Adeoti wa ni ikale nigba ti mo jade;
                           (v) ko dara ki eniyan maa se ibi.