Sedamo isori oro ti awon oro ti a fala si nidii wonyi je.
(I) Wahala omo naa ti pin mi lemii.
(II) Oro owo ile eko awon omo wahala mi pupo
(III) Iya ibeji ko suegbe to beyen.
(IV) Aye ko si fun suegbe ni Eko.
(V) Ise gbajue ni Sola yan laayo.
(VI) Gbajue ki i se oruko rere.
(VII) Kemokemo ti o n rin lo yo o
(VIII) A ti mo Ade mo irin kemokemo.
(IX) Idowu n rin kemokemo
(X) Jeje ni omo Olorun n se.