Se agbeyewo okookan awon gbolohun wonyi, ki o si dahun ibeere ti o tele won.
(a)(i) Mo n fa a
(ii) A mo on.
(iii) Won ran wa si i.
(iv) E gbodo ran mi lo
(v) Ise yin ti pari lodo re.
(b) Iru oro-aropo-oruko wo ni a fala si nidi?
(d) Ise wo ni okookan won se ninu gbolohun ti o wa?